Agbarijọpọ awọn ẹgbẹ ajafẹtọmọniyan bii mẹrinla ọtọọtọ ti koro oju si iwa ifipabanilopọ ati iṣekupani ti awọn obinrin n koju lawujọ. Ninu ipade awọn oniroyin to waye lopin ọsẹ yii niluu Ibadan, awọn ...
Ajalu nla lo ṣẹlẹ lagbo ere bọọlu liigi orilẹede Naijiria pẹlu iku agbabọọlu Niger tornadoes, Hussaini Isiah, ni irọlẹ ọjọ aje. Gẹgẹ bi iroyin ṣe sọ, iku wọle ti Hussaini Isiah, nigba ti ọlọkada kan ...